[00:00.000] 作曲 : Erik Steen[00:00.005] 制作人 : ERIICE[00:00.010]Balẹ̀[00:01.730]Balẹ̀[00:06.660]Balẹ̀[00:10.750]Balẹ̀[00:15.280]Iná ń'ọkàn mi[00:18.000]Ọ n jó bi iná[00:20.240]Ifẹ̀ re tí mu mi[00:21.840]Ko wun mi ka ma ṣepe[00:23.580]Òjò nlá tí mo ri[00:26.030]Ifẹ̀ rẹ ti n ṣo mi dédé[00:27.880]Mo mo pe eeyan ni[00:30.430]Ko ni fi mi s'ílẹ̀[00:31.730]Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀[00:33.740]L'ójú rẹ ni mo wa[00:35.620]Eyin temi ni gbogbo re[00:37.730]O loju mi bi kékeré[00:39.690]Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀[00:41.810]L'ójú rẹ ni mo wa[00:43.840]Eyin temi ni gbogbo re[00:45.970]O loju mi bi kékeré[00:48.050]Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀[00:50.040]Balẹ̀[00:55.730]Ọkàn balẹ̀[00:58.650]Ẹyin temi ni gbogbo re[01:02.650]O loju mi bi kékeré[01:04.600]Àtún wa ni ayé[01:07.420]Ifẹ̀ a ma p'ata[01:09.310]O ma dùn bi oyin[01:11.320]Iná n'ọkàn mi[01:13.360]Rántí ọjọ́ ti o si mi[01:16.030]Ifẹ̀ ti e gbe mi le[01:17.920]Mo mo pe eeyan ni[01:20.230]Ko ni fi mi sile[01:21.670]Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀[01:23.270]L'ójú rẹ ni mo wa[01:25.270]Eyin temi ni gbogbo re[01:27.350]O loju mi bi kékeré[01:29.390]Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀[01:31.700]L'ójú rẹ ni mo wa[01:33.930]Eyin temi ni gbogbo re[01:35.660]O loju mi bi kékeré[01:40.510]Balẹ̀[01:46.510]Balẹ̀[01:50.240]Balẹ̀[01:55.420]Balẹ̀[01:58.860]Balẹ̀[02:03.450]Ọkàn balẹ̀[02:06.690]Eyin temi ni gbogbo re[02:08.790]O loju mi bi kékeré[02:10.850]Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀[02:12.830]L'ójú rẹ ni mo wa[02:14.750]Eyin temi ni gbogbo re[02:17.040]O loju mi bi kékeré[02:18.970]Ọkàn mi ni f'ọkàn balẹ̀[02:21.110]L'ójú rẹ ni mo wa[02:23.020]Eyin temi ni gbogbo re[02:25.270]O loju mi bi kékeré